Download PDF
Back to stories list

Mo fẹ́ràn kàwé I like to read!

Written by Letta Machoga

Illustrated by Wiehan de Jager, Vusi Malindi

Translated by Blessing Williamson, Victor Williamson

Language Yoruba

Level Level 1

Narrate full story The audio for this story is currently not available.


Mo fẹ́ràn kàwé.

I like to read.


Mo máa n kàwé pẹ̀lú ọ̀rẹ́ mi.

Who can I read to?


Olùkọ́ mi ń rán mi lọ́wọ́ láti kàwé.

My sister is asleep.


Tani mo lè kàwé sí i?

Who can I read to?


Mo ń kàwé pẹ̀lú àwọn ọ̀rẹ́ mi.

My mother and grandmother are busy.


Tani mo lè kàwé sí i?

Who can I read to?


Bàbá àti bàbá bàbá mi ń ṣiṣẹ́.

My father and grandfather are busy.


Tani mo lè kàwé sí i? Mo lè kàwé fúnara mi!

Who can I read to? I can read to myself!


Written by: Letta Machoga
Illustrated by: Wiehan de Jager, Vusi Malindi
Translated by: Blessing Williamson, Victor Williamson
Language: Yoruba
Level: Level 1
Source: I like to read from African Storybook
Creative Commons License
This work is licensed under a Creative Commons Attribution 3.0 International License.
Options
Back to stories list Download PDF