Àgùfọn méjì fẹ́ lọ mu omi.
两只长颈鹿去喝水。
Ẹfọ̀n mẹ́ta àti ẹyẹ mẹ́rin fẹ́ lọ mu omi.
这里有三头水牛和四只鸟,全部都要去喝水。
Ẹtu márùnún àti túrùkú mẹ́fà ń rìn lọ sí ibi omi.
五只高角羚和六只疣猪走去喝水。
Sẹ́bírà méje ń sáré lọ mu omi.
七匹斑馬跑去喝水。
Kọ̀ǹkọ̀ mẹ́jọ àti ẹja mẹ́sànàn ń wẹ̀ nínú omi.
水中有八只青蛙,也有九条鱼。
Kìnìún kan bú ramúramù.Òun náà fẹ́ mu omi
Tani ń bẹ̀rù kìnìún?
一头狮子吼叫着。
他也想喝水。
谁怕狮子了?
Erin kan ń mu omi pẹ̀lú kìnìún.
一头大象和狮子一起喝水。